COVideo19: Bloomberg School Translate the Science in Yoruba

Aworan agbelewo ti COVID-19 o je ohun ti a gbe kale ti awon omo ile iwe ati ti Alaboju ti Johns Hopkins ni bi itoju ara nbgiyanju lati se itankale imo ijinle ti o ye yekeyeke nipa COVID-19 ni oni ru nru ede pupo. A fe je ki oro yin lorun pelu awon ololufe yin lati mo bi a se le wa ni idaabo bo nigba ajakale arun ti o ti mu emi opolopo lo ni gbogbo agbaye. E jowo e se alaba pin aworan agbelewo yi ki gbogbo eniyan le mo wipe e feran wan. #COVID19 #coronavirus #jhsph #flattenthecurve #Pandemic

For information about our project in English, and links to our videos in many more languages, please visit here.

Eniti o nse alaye: Dr. Opeyemi Oladapo-Shittu

 

 

View GHN’s latest coronavirus news.

For the latest, most reliable COVID-19 insights from some of the world’s most respected global health experts, see Global Health NOW’s COVID-19 Expert Reality Checks.

Join the tens of thousands of subscribers who rely on Global Health NOW summaries and exclusive articles for the latest public health news. Sign up for our free weekday newsletter, and please share the link with friends and colleagues: https://www.globalhealthnow.org/subscribe